The state of Osun Anthem,Yoruba and English.

ORIN ÀKOWÚRÍ ÌPÍNLÈ ÒSUN

1. Isé wa fún Ilè wa,
Fún Ilè ìbí wa,
K’á gbega, k’á gbega,
k’a gbega fun aiyé rí.

2. Ìgbàgbó wa ni wípé,
Bí a se bí erú ni a bí omo
K’a sisé, k’a sise
K’a sisé k’a jolà.

3. Ìsòkan àti òmìnira,
Ni ki á mã lepa,
‘Tèsíwájú òpò ire
Àti ohun tí ó dára.

4. Omo Óoduà dìde,
Bósí ipò ètó re,
Ìwo ni ìmólè
Omo Adúláwò.

STATE OF OSUN ANTHEM

1. Our work for our land,
For the land of or birth,
Let’s lift it up (3ice),
For the world to see.

2. Our belief is
That the slave is birthed as a freeborn,
Let’s work (3ce),
So we can together prosper.

3. Unity and freedom,
Should be our common pursuit,
Progress, fortunes and all that’s good.

4. Children of Oòduà rise up,
Come to your rightful position,
You are the light
Of all the Black race.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

54 + = 64